Kizz Daniel – Pano Tona Instrumental (Prod. Philkeyz)
Instrumentals
Nigerian singer Kizz Daniel features Simi's husband, Adekunle Gold, on this hot banger, "Pano Tona." It was released on 11/11/2024 through Flyboy Inc./Empire.
Below is the instrumental of this beautiful masterpiece.
Pano Tona
Kizz Daniel
Pano Tona Lyrics
Vado
Ob', Obah
Banger
K'Oluwa gbe wa gẹgẹ o
K'aye ma fi wa ṣẹfẹ
Ki n ra mọto, ki n ma f'ẹsẹ ṣa
K'ọla mi de, k'ọla mi pọ ṣa
T'aye ba gbe ẹ leke
Wọn tun ma gbe ẹ ṣepe (Ọlọhun)
Ọmọ gutter to n fly by jet
Ice water lo n fa ongbẹ
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tan'na
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun ṣana si o, Vado
Ọla Oluwa ni (ọla Ọlọrun ni o)
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun n tan'na
B'ọn ṣe n pana mi, mo tun ṣana si o, Vado
Ọla Oluwa ni
Blessings follow me differently
O yatọ s'awọn t'ẹlomi
After many, many hits
After destinambari
Don't want your validation flower
I be who I say I am (Vado)
I no dey fancy the lifestyle
I just wan sing (fun awọn fans wa)...
MAIN ARTIST |
---|
ABOUT KIZZ DANIEL |
---|
Oluwatobiloba Daniel Anidugbe, better known as Kizz Daniel, is a Nigerian singer and songwriter.
FEATURED ARTIST(s) |
---|
Adekunle Gold |
POSTS KIZZ DANIEL FEATURED |
---|
LATEST FROM KIZZ DANIEL |
---|
RECENT POSTS |
---|